Simi - Bring Back Our Kids - Oyo ABDUCTION song
SECURITY EMERGENCY HOTLINES IN OYO STATE!
NI ogan ti e bati kefin tabi rii aridaju awon onise ibi e pee SI number toll 615 ni ipinle Oyo. Oyo Police Command 08081768614 tabi 07055495413
Bakanna SI AWON Amotekun NI agbegbe Afijio 0814 831 0147, ATIBA 0803 568 0940, OYO EAST 08133598799, OYO WEST 09037110726.
Hi, I’m using WalkTask to earn money by walking every day. Enter my invitation code: 997K7Y ,and you’ll receive a bonus of up to $10! The bonus has no requirements and will be automatically transferred to your PayPal within minutes!
Google Play: https://play.google.com/store/....apps/details?id=com.
App Store: https://apps.apple.com/us/app/....walktask-walk-work-g
O doju e... O doju ogbagadagbi bayii! Eto abo ara wa ati Ilu ti doju e.
O wa doju re bayii o.!
(2nd Voice panicking.) . . Kinni ka wa se bayii?
Ohun ti a o se wa, to po. Watch on YouTube https://youtu.be/pB4ipKyO4Hg
Eto abo o ti dandan fun gbogbo wa lati mo ju to.
Onile ati alejo, majesin ati agbalagba, gbogbo wa ni ki a fi oju alakan wa fii s'ori. Ohun ti o kan ara Iwo o kan ara Ede.. Ti a ba ti ri onnkan ti o mu ifura dani, ti o le se agbako Ohun wahala idarudapo si inu Ilu, tabi irinkinri ti o mu ifura dani. Agbenipa won o ni mu wa lo o. Oro yii KO se da ijoba tabi enikankan bi KO se ara wa, gbogbo wa pata ni a gbudo fi Owo sowopo ki a fi sowopo LORI eto abo ni agboole SI agboole, ahoro SI woro, opopona SI opopona, abule sabule, ileto ati awon igberiko wa. Ki a fi owosopo ni adugbo wa. Oju ni alakan fi n sori. Ni kanmo ti a ba kefin awon onise ibi, ni ki a ridaju pe - a fi to awon eleto abo ti o sunmo wa, e FI to agbofinro leti,
Eni onise ibi ti Owo wa ba ti te, e je kafa a le awon otelemu yen, e fa le awon agbofinro lowo.
Ilu wa ni Ilu wa, Ko gbudo baje,
NI ogan ti e bati kefin tabi rii aridaju awon onise ibi e pee SI number toll 615 ni ipinle Oyo. Oyo Police Command 08081768614 tabi 07055495413
Bakanna SI AWON Amotekun NI agbegbe Afijio 0814 831 0147, ATIBA 0803 568 0940, OYO EAST 08133598799, OYO WEST 09037110726.
Aabo Ilu ti Di Owo emi ati eyin. O di owo gbogbo wa!
OYO ALAAFIN IN DIASPORA ...lo mu itanilobo yii wa fun yin.
https://www.facebook.com/share/p/1FvXWVbQZ6/
*AABO ARA WA NI AABO ILU.. OYO ALAAFIN IN DIASPORA n kede*!
Watch on YouTube https://youtu.be/pB4ipKyO4Hg
@highlight
0 Kommentarer